BLOG
Some Yoruba Tips (2022-08-21 18:33:15 )
Ọ̀NÀ MÁRÙN-ÚN TÍ ỌKÙNRIN MÁA Ń GBÀ DÉ FÌLÀ GỌ̀BÌ ÀTI ÌTUMÒ WỌN*
*Apá òsì:* Èyí wà fún ọkùnrin tó ti di Aláya nílé
*Apá ọ̀tún:* Èyí wà fún àpọ́n lỌ́kùnrin
*Gígẹ fìlà síwájú:* Èyí túmọ̀ sí ọkùnrin tí ayé ti sú
*Ki fìlà ga gogoro:* Tí ọkùnrin bá dé fìlà gogoro èyí ń ṣe àfihàn ìwà ìgbéraga
*Gígẹ fìlà sẹ́hìn:* Èyí ń ṣe àpèjúwe ọkùnrin tí kò bìkítà nípa nǹkan kan.
_Mo rọ gbogbo àwa ọkùnrin kí á máa kíyèsi bi a ti ṣe ń dé Fìlà wa láti òní lọ nítorí bí a ti ṣe ń rìn làá ń koni._
*ISOOF®️ 2019*
YORUBA TIMES OF THE DAY
*OWURO.................. 6 - 10 am*
*IYALETA.................. 10 - 12 am*
*OSAN..................... 12 - 4 PM*
*IROLE..................... 6 - 7 PM*
*ASALE/ALE............. 7 - 10 PM*
*ORU*...................... 11PM - 12 AM
*OGANJO.................. 12 - 2 AM*
*AAJIN....................... 2 - 3 AM*
*AFEJUMO..................... 4am to 5am*
Please educate yourself and your children.